VOOZH about

URL: https://yo.wikipedia.org/wiki/Common_Era

⇱ Common Era - Wikipedia, ìwé-ìmọ̀ ọ̀fẹ́


Jump to content
Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
👁 Image
Àwòrán tí ó ń tọ́ka Common Era

CE àti AD jẹ́ kannáà, ṣùgbọ́n àwọn ènìyàn tí ko gbàgbọ́ nínú Jésù Kristi tàbí Ọlọ́run, ni wọ́n ń lo CE dípò AD. Ní èdè Gẹ́ẹ́sì (English) CE èyí túmọ̀ sí «Common Era» ìtumọ̀ ní èdè Yorùbá jẹ́ Àsìkò tó wọ́pọ̀.