VOOZH about

URL: https://yo.wikipedia.org/wiki/Main_Page

⇱ Wikipedia


Jump to content
Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Main Page)
Ẹ kú àbọ̀Wikipedia,
ìwé-ìmọ̀ ọ̀fẹ́ẹnikẹ́ni le túnṣe.
00:21 (UTC); Ọjọ́ Àbámẹ́ta, Ọjọ́ 4 Oṣù Igbe ọdún 2026
Àyọka 37,047l'èdè Yorùbá.
Àwọn èbúté·Àwọn ẹ̀ka·Ìrànlọ́wọ́

Ìlànà· Àwọn Ìbéèrè Wíwọ́pọ̀· Àgbàjọ· Àwọn ìpinu ọ̀nà ìṣiṣẹ́ Wikipedia· Ọrẹ· WAP· Ibi Ìṣojú (Embassy)· Ìbápàdé

👁 Adeniran Ogunsanya, amòfin àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Adeniran Ogunsanya, amòfin àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

Adeniran Ogunsanya QC, SAN (31 January 1918 – 22 November 1996) jẹ́ amòfin àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí ó sì tún jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára àwọn olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú Ibadan Peoples Party (IPP). Ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí Kọmíṣọ́nà fún ètò ìdájọ́ ati ètò ẹ̀kọ́ fún Ìpínlẹ̀ Èkó ní àsìkò ìṣèjọba alágbádá ẹlẹ́kejì. Òun náà tún ni alága pátá pátá fún ẹgbẹ́ òṣèlú Nigerian People's Party nígbà ayé rẹ̀. Wọ́n bí Adéníran ní ọjọ́ Kọkànlélógún oṣù Kíní ọdún 1918 ní agbègbè ÌkòròdúÌpínlẹ̀ Èkó sí agboolé ọmọ Ọba Sùbérù Ògúnsànyà Ògúntádé tí ó jẹ́ Ọdọ̀fin ti ìlú Ìkòròdú nígbà náà. Adéníran lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti Hope Waddell Training Institute ní ìlú Calabar nígbà tí ó ń gbé pẹ̀lú àbúrò bàbá rẹ̀ tí ó jẹ́ òṣìṣẹ́ ìjọba ní ìlú Calaba. Ìjọba fi ẹ̀bùn ẹ̀kọ́-ọ̀fẹ́ dá Adéníra lọ̀lá láti kàwé síwájú si ní ilé-ẹ̀kọ́ King's College tí ó wà ní Ìpínlẹ̀ Èkó látàrí bí ó ṣe peregedé jùlọ pẹ̀lú máàkì tí ó ga jùlọ nínú ìdánwò àṣekágbá ti Standard VI (6) ní ọdún 1937. Ó tẹ̀ siwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀, tí ó sì kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ òfin ní ilé-ẹ̀kọ́ fásitì ti University of Manchester àti Gray's Inn tí ó jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ ìmọ̀ òfin.

(ìtẹ̀síwájú...)

👁 Image

👁 Image
Ẹ tún wo ÌròyìnWiki ní èdè Gẹ̀ẹ́sì
👁 Image

Igbá ẹ̀yìn ìgbín odò Dendroconus figulinus.

👁 Image
Àwọn Iṣẹ́-ọwọ́ Míràn
Wikimedia Foundation ni ó gba àlejò Wikipedia, egbe-alasepo ti ki se fun ere ti o tun se alejo opo awon ise-owo miran:
👁 Wikiàyásọ
Wikiàyásọ
Àkójọ àwọn àmúsọ
👁 Wikiatúmọ̀èdè
Wikiatúmọ̀èdè
Atúmọ̀èdè orísirísi èdè
👁 Wikispecies
Wikispecies
Àkójọ àwọn irú ẹ̀dá
👁 Wikiìròyìn
Wikinews
Ìròyìn ọ́fẹ̀
👁 Wikisource
Wikisource
Àwọn àkọsíìwé ọ̀fẹ́
👁 Commons
Wikimedia Commons
Àwòrán, ìró àti fídéò
👁 Wikifásítì
Wikifásítì
Èlò ìkọ́ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́
👁 Wikiìwé
Wikiìwé
Ìwéẹ̀kọ́ àti ìwéàwòṣe ọ̀fẹ́
👁 Meta-Wiki
Meta-Wiki
Ibi àkóso ìṣẹ́-ọwọ́ Wikimedia
👁 Wikidata
Wikidata
Ìbùdó ìmò ọ̀fẹ́


👁 Image
Àṣà

Lítíréṣọ̀Eré-ìdárayáFílmùOrinTíátàÌṣeròyìnTẹlifísànRédíò

👁 Image
Tẹknọ́lọ́jì

Iṣẹ́ẹ̀rọInternetÀfigbébánisọ̀rọ̀Kọ̀mpútà

👁 Image
Àwùjọ

ẸbíFàájìÒfinỌ̀rọ̀-òkòwòÌnáwóÌṣèlúỌ̀rọ̀-àwùjọÈnìyànẸ̀kọ́Ìmòye

👁 Image
Sáyẹ́nsì

Ìtòràwọ̀ÒfurufúỌ̀gbìnSáyẹ́nsì kọ̀mpútàFísíksìÌwòsànÀdánidáKẹ́místrìBàíọ́lọ́jì

👁 Image
Mathimátíkì

Áljẹ́bràÌtúwòÌṣíròÌṣedọ́gbaJẹ́ọ́mẹ́trìNọ́mbàTẹ̀ọ́rẹ́mùỌgbọ́n

👁 Image
Jẹ́ọ́gráfì

AyéAdágúnOrílẹ̀-èdèÒkunOrílẹ̀ÌlúÁfríkàÁsíàEuropeGúúsù Amẹ́ríkàÀríwá Amẹ́ríkà

👁 Image
Ìtàn

OgunOrílẹ̀-èdè tẹ́lẹ̀Ilẹ̀ọbalúayéỌ̀rọ̀-ayéijọ́un

👁 Image
Ìgbésíayé

Olórí orílẹ̀-èdèOníṣọ̀nàÒṣeréOnímọ̀sáyẹ́nsìAmòyeOlóṣèlúOlùkọ̀wéOníṣòwò

👁 Image
Ẹ̀sìn àti ìgbàgbọ́

Ẹ̀sìn YorùbáÌmàleẸ̀sìn KrístìÌṣebúddhàÌṣehíndù

👁 Image
Ìlera

ÌmáralókunÌdárayáAmáralókunìtọ́jú ìleraÀrùnỌ̀rọ̀-àjàkálẹ̀àrùn